MO GBOGO
I Receive Glory
Cho –
Call: Mo gbogo o mogbogo
Res: Irina ajo moba jesu lo o mogbogo
Call: Mo gbogo o mogbogo
Res: Irina ajo moba jesu lo o mogbogo (Refrain)
Voc 1: Mogbogo fun ara mi,
Mogbogo fun omo mi,
Mogbogo fun aya mi,
Mogbogo funse mi o,
Mogbogo fun aye mi.
Voc 2: Ogo owuro, ogo osan ogo ale, baba fifun mi,
nitori kos eni tole fowo bo ogo osupa,
enikan Ole mu ojo o komayo,
irawo owuro baba fifun mi,
irawo ale baba ti fun mi niyen ke moyo
(Repeat Chorus)
(Fast Beat)
Cho: Mosun moji, mosun moji, mosun moji, (2x)
Res: mosun moji oooo (2x)
2x
Cho: Moji moyo mosope, moji moyo mosope
mosope fun eledumare oba oke oba ile, (2x)
Oba to dawa si, Oba to Pawan mo ninu ewu oru
Opeyele re o baba
(Opeyelere o baba)
Voc: Emi fi ohun mi ke si olwa osi dami lohun lati oke mimore wa,
Emi dupe mosun mosiji nitori oluwa timi lehin
Emi ki o beru opolopo eniyan ti won rogba yimika,
Toripe oluwa unbe lehin mi bi akoni eleru mogbe o ga
mogbe o ga baba
Interlude
Call: Oluwa Res: Iwololrun mi oo
Call: Oluwa Res: Iwololorun mi oo
Cho : Ni kutukutu lemi o ma saferi re,
ohungbe re ungbe okan mi o,
eran ara mi fasi o Nile gbigbe ati ile tinpoungbe,
nibiti omi kogbe si rare baying ni emin tiunwo e o
lati ibi mimo re wa lati ri agbara re ati ogo re,
Call: Ilekun Res: anu mi o
Call: Ilekun Res: anu mi o
Si fun mi Baba
si fun mi Omo
si fun mi Emin Mimo, kinle raye wole sinu ogo re, (rep)
Call: Oluwa jowo funmi la anu unla Res: Oluwa jowo funmi la anu unla
Call: Oluwa jowo gbere temi komi o Res : Oluwa joko funmi la anu unla
Cho : Great mercy, great mercy,
great mercy is what I wont, fi fun mi,
Great mercy, great mercy,
great mercy is what I wont fi fun mi
Interlude
Ver: Mayin Jesu logo oo,
mayin Jesu logo oo
mayin Jesu logo oo
mayin Jesu logo oo, nitori pe,
ohun loni gbogbo ogo eledunmare,
ohun loni gbogbo ogo eleru ni’yin o
mayin Jesu logo o
Iwo nko?
Cho: Mayin Jesu logo oo,
mayin Jesu logo oo
mayin Jesu logo oo
mayin Jesu logo oo, nitori pe,
ohun loni gbogbo ogo eledunmare,
ohun loni gbogbo ogo eleru ni’yin o
mayin Jesu logo o
Call: Mayin Jesu logo o Res: Mayin Jesu logo o (2x)
Call: Alagbara nla Res: Mayin Jesu logo o
Call: Oga ogo o Res: Mayin Jesu logo o
Cho : Great mercy, great mercy,
great mercy is what I wont, fi fun mi,
Great mercy, great mercy,
great mercy is what I wont fi fun mi
2x